DictionaryForumContacts

   English Yoruba
A B C D E F G H I J K L M N O P Q R S T U V W XZ   <<  >>
Terms for subject Microsoft (3738 entries)
Sharpen and Soften Ète Ìmúsí Àwòrán
sheet ojú-ìwé
sheet tab táàbù aṣíjúewé
shell ṣẹ́ẹ̀lì
SHIFT key bọ́tìnnì SHIFT
shipping address ibi ìgbọ́jàlọ
shipping label àkọlé àfiṣọwọ́
shortcut àbùjá
shortcut group ẹgbẹ́ ọ̀nà àbùjá
shortcut key bọ́tìnnì àbùjá
shortcut menu mẹ́nù Àbùjá
Shortcuts pane Ààyè àwọn ọ̀nà àbùjá
show ṣàfihàn
shrink súnkì
shuffle yọ ọ́ kọ
shut down pa á
Shut Down Pa á
shutdown ìpa
sidebar Òpó-ẹ̀gbẹ́
Sign In Wọlé